Delivered-To: toyin....@mail.utexas.edu
X-IronPort-MID: 418030316
X-SBRS: 4.6
X-IronPort-Anti-Spam-Filtered: true
X-IronPort-Anti-Spam-Result: AgAAAPgXjkfRVZL5kmdsb2JhbACCcI0lAgEBBwIGCQoWnUw
X-IronPort-AV: E=Sophos;i="4.24,297,1196661600";
d="scan'208";a="418030316"
X-Apparently-To: yorubaaff...@googlegroups.com
Authentication-Results: mx.google.com; spf=pass (google.com: domain of missiona...@yahoo.com designates 209.191.85.235 as permitted sender) smtp.mail=missiona...@yahoo.com; domainkeys=pass (test mode) header.From=missiona...@yahoo.com
X-YMail-OSG: pTQpAXoVM1lpB48AU4GH7HmxtaOnLgN2w7Fo4BJC
Date: Wed, 16 Jan 2008 14:46:33 -0800 (PST)
From: Sayo Ajiboye <missiona...@yahoo.com>
Subject: Re: Yoruba Affairs - Yoruba Poem
To: yorubaaff...@googlegroups.com
X-Google-Loop: groups-owner
Arakunrin Adekunle
Iyanju lati ranti aroko naa ni eyi ti mo ko si isale yi... O ti fere e to ogoji odun ti a ti ko o sugbon mo tiraka lati gbiyanju iranti die.
Elomiran laarin awon amoye ati awon ojogbon ori eto yi lee fi enu si oro naa
Yoruba duun ka, O duun ko! O duun gbo leti!
TRANSLATION
This is an attempt at remembering... It is the better part of 40 years! Someone else can fill in or correct. Yoruba language is a beauty, to write, to read and to listen to!
Sayo Ajiboye,
Omo Oba, Alufaa Olorun Nla
Bellevue WA USA
ISE NI OOGUN ISE
Ise Ni OOgun Ise
Mura si ise ore mi
Ise ni a fii di ni giga
Bi a ko ba reni fehinti
bi ole laa ri
Bi a ko ba reni gbekele
A tera mo ise eni
Apa lara
Igunpa ni Iyekan
Baba re lee lowo lowo
Iya re lee lesin lekan
Bi o ba gboju le won,
O te tan ni mo so fun
Se ohun ti a ko ba jiya fun
Se kii lee to ojo
Ohun ti a ba fi ara sise fun
Nii pe lowo eni
Mura si ise ore mi
Ise ni a fii di eni giga
"Adekunle, Julius" <jade...@monmouth.edu> wrote:
Good day all:I ask for the favor of any one who has the version of Yoruba poemIse no ogun iseMura sis ore miI am using this poem for a paper. Kindly send it to me. Thank you.Julius Adekunle
Be a better friend, newshound, and know-it-all with Yahoo! Mobile. Try it now.
--
From: sarah anyang <agbor...@yahoo.com>
Subject: Re: Yoruba Affairs - Yoruba Poem
To: yorubaaff...@googlegroups.com
X-Google-Loop: groups-owner
Hi,
This how far i could go. sorry.
Ise ni i Ogun ise
Ise lafii di eni giga
Mura si ise ore mii
bi ako ba leni fehinti
Bi ole la rii
Bi akoba lenigbekele
Atera mo ise ni
baba re le lowolo
iya re sile lesin ile nkan
bi o ba gboju lewon
oti te tan ore mi
sorry. i am not an authority. perhaps this can joggle your memory......
----- Original Message ----
From: "Adekunle, Julius" <jade...@monmouth.edu>
To: yoruba...@googlegroups.com
Sent: Wednesday, January 16, 2008 1:24:01 PM
Subject: Yoruba Affairs - Yoruba Poem
Good day all:
I ask for the favor of any one who has the version of Yoruba poem
Ise no ogun ise
Mura sis ore mi
I am using this poem for a paper. Kindly send it to me. Thank you.
Julius Adekunle
Looking for last minute shopping deals? Find them fast with Yahoo! Search.