Re: Yoruba Affairs - Re: AJO YORUBA IGBALODE - APPLIED YORUBA GROUP

3 views
Skip to first unread message

ogun...@fiu.edu

unread,
Oct 13, 2006, 12:08:13 PM10/13/06
to yoruba...@googlegroups.com, Prof. Antonia Yetunde Schleicher, Dr. Samuel Olamijulo, Adebusola Onayemi, Dr. Kayode Fakinlede, Prof. Michael Faborode, Prof. Oluropo Sekoni, Secretary YorubaNation, Dr Tunde Adegbola, Prof. Toyin Falola
Mo kin imo.ran Ojo.gbo.n Owomoyela le.yin pe.lu afikun. Gegebi o s.e je. pe O.jo.gbo.n Falo.la lo be.re. ajo. ifinukonu Yoruba lori e.ro itanka (internet) ti a nlo bayi pelu igbekale. yoruba...@googlegroups.com, ki ba dara to ba le je pe Applied Yoruba Group a wa ge.ge.bi e.ka Yoruba Affairs. A gbaruku ti won ki is.e. na ma wo.n lo.run

Ko ni re. wa o
E. s.e pupo.

Akin Ogundiran
Associate Professor of History
Director, African-New World Studies
Florida International University
Biscayne Bay Campus, AC1-163B
3000 N.E. 151st Street
North Miami, FL 33181
Tel. 305-919-5521
Fax. 305-919-5267
www.fiu.edu/~africana

Dr. Samuel Olamijulo

unread,
Oct 13, 2006, 3:10:37 PM10/13/06
to yoruba...@googlegroups.com, Prof. Antonia Yetunde Schleicher, Dr. Samuel Olamijulo, Adebusola Onayemi, Dr. Kayode Fakinlede, Prof. Michael Faborode, Prof. Oluropo Sekoni, Secretary YorubaNation, Dr Tunde Adegbola, Prof. Toyin Falola, Prof. Kola Thomas, ogun...@fiu.edu
E ku ikale o,
Mo ki imonran Ojogbon Owomoyela ati afikun Ojogbon Ogundiran lehin nipa ipa ti o wulo pupo ti Ojogbon Falola a jowo lati ba wa ko fun igbekale ati itesiwaju ajo yi.
 
Gbogbo wa si tun le ri wipe ise ti Ojogbon Fakinlede ti ngbese wulo pupo lati mulo ninu igbekale ati itesiwaju ajo yi. Amoran won wipe ki a fi bi ose kan si gba awon ololufe tuntun ti o fe nipa ninu ise ajo yi mora, ki a si fi ori ba ori lori kini awon ohun pato ti a fe ki ajo yi duro fun fa ogbon yo.
 
Ojogbon Kola Thomas ti so ipa ti awon le ko lati mu ise se.
 
Oro gidi ni wipe ajo ko gbodo je ki ise yi wo awon eniyan die lorun. Gbogbo wa nilati se ohun ti a le se lati ru eru ti o wa ni iwaju.
 
Ire o.
 
Dokita Samuel Kayode Olamijulo
-----------------------------------------------------


Talk is cheap. Use Yahoo! Messenger to make PC-to-Phone calls. Great rates starting at 1¢/min.

Reply all
Reply to author
Forward
0 new messages